Jer 14:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awa jẹwọ iwa buburu wa, Oluwa, ati aiṣedede awọn baba wa: nitori awa ti ṣẹ̀ si ọ.

Jer 14

Jer 14:15-22