Jer 10:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Egbe ni fun mi nitori ipalara mi! ọgbẹ mi pọ̀: ṣugbọn mo wipe, nitõtọ ìya mi ni eyi, emi o si rù u.

Jer 10

Jer 10:9-25