Jer 10:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa wi, sa wò o, emi o gbọ̀n awọn olugbe ilẹ na nù lẹ̃kan yi, emi o si pọ́n wọn loju, ki nwọn ki o le ri i.

Jer 10

Jer 10:13-23