Jak 4:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin bère, ẹ kò si ri gbà, nitoriti ẹnyin ṣì i bère, ki ẹnyin ki o le lò o fun ifẹkufẹ ara nyin.

Jak 4

Jak 4:1-10