Isa 8:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Niwọn bi enia yi ti kọ̀ omi Ṣiloa ti nṣàn jẹjẹ silẹ, ti nwọn si nyọ̀ ninu Resini ati ọmọ Remaliah.

Isa 8

Isa 8:1-8