Isa 7:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

A si sọ fun ile Dafidi pe, Siria ba Efraimu dìmọlú. Ọkàn rẹ̀ si mì, ati ọkàn awọn enia rẹ̀ bi igi igbo ti imì nipa ẹfũfu.

Isa 7

Isa 7:1-12