Isa 3:17-19 Yorùbá Bibeli (YCE)

17. Nitorina Oluwa yio fi ẽpá lu atàri awọn ọmọbinrin Sioni, Oluwa yio si fi ihoho wọn hàn.

18. Li ọjọ na Oluwa yio mu ogo ṣaworo wọn kuro, ati awọn ọṣọ́ wọn, ati iweri wọn bi oṣupa.

19. Ati ẹ̀wọn, ati jufù, ati ìboju,

Isa 3