Isa 27:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Irunú kò si ninu mi: tani le doju pantiri ẹlẹgun ati ẹgun kọ mi li ogun jijà? emi iba là wọn kọja, emi iba fi wọn jona pọ̀ ṣọ̀kan.

Isa 27

Isa 27:2-13