Isa 27:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi Oluwa li o ṣọ ọ: emi o bù omi wọ́n ọ nigbakugba: ki ẹnikẹni má ba bà a jẹ, emi o ṣọ ọ ti oru ti ọsan.

Isa 27

Isa 27:1-7