Isa 25:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA, iwọ li Ọlọrun mi; emi o gbe ọ ga, emi o yìn orukọ rẹ; nitori iwọ ti ṣe ohun iyanu; ìmọ igbani, ododo ati otitọ ni.

Isa 25

Isa 25:1-3