Isa 22:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ọjọ wahála ni, ati itẹmọlẹ, ati idãmu, nipa Oluwa, Oluwa awọn ọmọ-ogun ni afonifoji ojuran, o nwó odi palẹ, o si nkigbe si oke-nla.

Isa 22

Isa 22:4-7