Isa 22:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina li emi ṣe wipe, Mu oju kuro lara mi; emi o sọkun kikoro, má ṣe ãpọn lati tù mi ni inu, nitori iparun ti o ba ọmọbinrin enia mi.

Isa 22

Isa 22:1-9