Isa 13:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi ti paṣẹ fun awọn temi ti a yà si mimọ́, emi ti pe awọn alagbara mi pẹlu fun ibinu mi, ani awọn ti nwọn yọ̀ ninu ọlanla mi.

Isa 13

Isa 13:1-5