Isa 12:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kigbe, si hó, iwọ olugbe Sioni: nitori ẹni titobi ni Ẹni-Mimọ́ Israeli li ãrin rẹ.

Isa 12

Isa 12:5-6