Isa 12:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ATI li ọjọ na iwọ o si wipe, Oluwa, emi o yìn ọ: bi o tilẹ ti binu si mi, ibinu rẹ ti yi kuro, iwọ si tù mi ninu.

Isa 12

Isa 12:1-6