Isa 11:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọmọ ẹnu-ọmu yio si ṣire ni ihò pãmọlẹ, ati ọmọ ti a já lẹnu-ọmu yio si fi ọwọ́ rẹ̀ si ihò ejò.

Isa 11

Isa 11:1-13