Isa 11:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Malũ ati beari yio si ma jẹ pọ̀; ọmọ wọn yio dubulẹ pọ̀; kiniun yio si jẹ koriko bi malũ.

Isa 11

Isa 11:1-9