Isa 11:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Õrùn-didùn rẹ̀ si wà ni ibẹ̀ru Oluwa, on ki yio si dajọ nipa ìri oju rẹ̀, bẹ̃ni ki yio dajọ nipa gbigbọ́ eti rẹ̀;

Isa 11

Isa 11:1-5