Isa 11:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹmi Oluwa yio si bà le e, ẹmi ọgbọ́n ati oye, ẹmi igbimọ̀ ati agbara, ẹmi imọ̀ran ati ibẹ̀ru Oluwa.

Isa 11

Isa 11:1-6