2. Sam 1:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si wi fun u pe Ẹjẹ rẹ mbẹ li ori ara rẹ; nitoripe ẹnu rẹ li o fi jẹwọ pe, Emi li o pa ẹni-àmi-ororo Oluwa.

2. Sam 1

2. Sam 1:7-25