2. Pet 1:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina emi ó mã mura lati mã mu nkan wọnyi wá si iranti nyin nigbagbogbo bi ẹnyin tilẹ ti mọ̀ wọn, ti ẹsẹ nyin si mulẹ ninu otitọ ti ẹnyin ni.

2. Pet 1

2. Pet 1:7-21