2. Pet 1:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li a ó pese fun nyin lọpọlọpọ lati wọ ijọba ainipẹkun ti Oluwa ati Olugbala wa Jesu Kristi.

2. Pet 1

2. Pet 1:8-12