2. Kro 5:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kò si ohun kan ninu apoti-ẹri na bikòṣe walã meji ti Mose fi sinu rẹ̀ ni Horebu, nigbati Oluwa fi ba awọn ọmọ Israeli dá majẹmu, nigbati nwọn ti Egipti jade wá.

2. Kro 5

2. Kro 5:3-14