2. Kro 33:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn o ṣe buburu li oju Oluwa, bi irira awọn orilẹ-ède, ti Oluwa le jade niwaju awọn ọmọ Israeli.

2. Kro 33

2. Kro 33:1-5