Ati iyokù iṣe Hesekiah ati iṣẹ rere rẹ̀, kiyesi i, a kọ wọn sinu iwe iran Isaiah woli, ọmọ Amosi, ani ninu iwe awọn ọba Juda ati Israeli.