2. Kro 24:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori Ataliah, obinrin buburu nì ati awọn ọmọ rẹ ti fọ ile Ọlọrun; ati pẹlu gbogbo ohun mimọ́ ile Oluwa ni nwọn fi ṣe ìsin fun Baalimu.

2. Kro 24

2. Kro 24:6-15