2. Kro 24:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si pè Jehoiada, olori, o si wi fun u pe, Ẽṣe ti iwọ kò bère li ọwọ awọn ọmọ Lefi, ki nwọn ki o mu owo ofin Mose, iranṣẹ Oluwa, lati Juda ati lati Jerusalemu wá, ati ti ijọ-enia Israeli fun agọ ẹri?

2. Kro 24

2. Kro 24:1-16