2. Kro 2:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn tani to lati kọ́ ile fun u, nitori ọrun ati ọrun awọn ọrun kò le gbà a? tali emi ti emi iba kọ́le fun u, bikòṣe kiki ati sun ẹbọ niwaju rẹ̀?

2. Kro 2

2. Kro 2:4-9