2. Kor 3:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn titi di oni oloni, nigbakugba ti a ba nkà Mose, iboju na mbẹ li ọkàn wọn.

2. Kor 3

2. Kor 3:9-18