2. Kor 3:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn oju-inu wọn fọ́: nitoripe titi fi di oni oloni ní kika majẹmu lailai, iboju na wà laiká soke; iboju ti a ti mu kuro ninu Kristi.

2. Kor 3

2. Kor 3:10-18