2. A. Ọba 15:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Menahemu si fi agbara gbà owo na lọwọ Israeli, ani lọwọ gbogbo awọn ọlọrọ̀, ãdọta ṣekeli fadakà lọwọ olukuluku enia, lati fi fun ọba Assiria. Bẹ̃ni ọba Assiria yipada, kò si duro ni ilẹ na.

2. A. Ọba 15

2. A. Ọba 15:12-27