2. A. Ọba 15:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe eyi ti o buru li oju Oluwa: on kò si lọ kuro ninu ẹ̀ṣẹ Jeroboamu ọmọ Nebati ẹniti o mu Israeli ṣẹ̀, li ọjọ rẹ̀ gbogbo.

2. A. Ọba 15

2. A. Ọba 15:8-25