Ifi 22:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori li ode ni awọn ajá gbé wà, ati awọn oṣó, ati awọn àgbere, ati awọn apania, ati awọn abọriṣa, ati olukuluku ẹniti o fẹran eke ti o si nhuwa eke.

Ifi 22

Ifi 22:11-21