Ifi 22:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ibukún ni fun awọn ti nfọ̀ aṣọ wọn, ki nwọn ki o le ni anfani lati wá si ibi igi ìye na, ati ki nwọn ki o le gba awọn ẹnubode wọ inu ilu na.

Ifi 22

Ifi 22:6-16