Ifi 18:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Angẹli alagbara kan si gbé okuta kan soke, o dabi ọlọ nla, o si jù u sinu okun, wipe, Bayi li a o fi agbara nla bì Babiloni ilu nla nì wó, a kì yio si ri i mọ́ lai.

Ifi 18

Ifi 18:14-22