Ifi 18:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yọ̀ lori rẹ̀, iwọ ọrun, ati ẹnyin aposteli mimọ́ ati woli; nitori Ọlọrun ti gbẹsan nyin lara rẹ̀.

Ifi 18

Ifi 18:14-24