Iṣe Apo 9:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Oluwa wi fun u pe, Mã lọ: nitori ohun elo àyo li on jẹ fun mi, lati gbe orukọ mi lọ si iwaju awọn Keferi, ati awọn ọba, ati awọn ọmọ Israeli:

Iṣe Apo 9

Iṣe Apo 9:12-24