Iṣe Apo 9:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si gbà aṣẹ lati ọdọ awọn olori alufa wá si ihinyi, lati dè gbogbo awọn ti npè orukọ rẹ.

Iṣe Apo 9

Iṣe Apo 9:8-21