Iṣe Apo 8:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ọkunrin kan wà, ti a npè ni Simoni, ti iti ima ṣe oṣó ni ilu na, ti isi mã jẹ ki ẹnu ya awọn ara Samaria, a mã wipe enia nla kan li on:

Iṣe Apo 8

Iṣe Apo 8:8-16