Iṣe Apo 8:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti gbogbo wọn bọla fun, ati ewe ati àgba, nwipe, ọkunrin yi ni agbara Ọlọrun ti a npè ni Nla.

Iṣe Apo 8

Iṣe Apo 8:6-12