Iṣe Apo 7:40 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn wi fun Aaroni pe, Dà oriṣa fun wa ti yio ma tọ̀na ṣaju wa: nitori bi o ṣe ti Mose yi ti o mu wa ti ilẹ Egipti jade wá, a kò mọ̀ ohun ti o ṣe e.

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:36-46