Iṣe Apo 7:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti awọn baba wa kò fẹ gbọ́ tirẹ, ṣugbọn nwọn tì i kuro lọdọ wọn, nwọn si yipada li ọkàn wọn si Egipti;

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:29-40