Iṣe Apo 5:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li olori ẹṣọ́ lọ pẹlu awọn onṣẹ, o si mu wọn wá kì iṣe pẹlu ipa: nitoriti nwọn bẹ̀ru awọn enia, ki a má ba sọ wọn li okuta.

Iṣe Apo 5

Iṣe Apo 5:19-28