Iṣe Apo 5:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li ẹnikan de, o wi fun wọn pe, Wo o, awọn ọkunrin ti ẹnyin fi sinu tubu wà ni tẹmpili, nwọn duro nwọn si nkọ́ awọn enia.

Iṣe Apo 5

Iṣe Apo 5:21-30