Iṣe Apo 4:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki iwọ si fi ninà ọwọ́ rẹ ṣe dida ara, ati ki iṣẹ àmi ati iṣẹ iyanu ki o mã ṣe li orukọ Jesu Ọmọ mimọ́ rẹ.

Iṣe Apo 4

Iṣe Apo 4:24-37