Iṣe Apo 4:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi, Oluwa, kiyesi ikilọ wọn: ki o si fifun awọn ọmọ-ọdọ rẹ lati mã fi igboiya gbogbo sọ ọ̀rọ rẹ.

Iṣe Apo 4

Iṣe Apo 4:19-33