Iṣe Apo 3:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Ọlọrun jí Jesu Ọmọ rẹ̀ dide, o kọ́ rán a si nyin lati busi i fun nyin, nipa yiyi olukuluku nyin pada kuro ninu iwa buburu rẹ̀.

Iṣe Apo 3

Iṣe Apo 3:22-26