Iṣe Apo 3:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin li ọmọ awọn woli, ati ti majẹmu tí Ọlọrun ti ba awọn baba nyin dá nigbati o wi fun Abrahamu pe, Ati ninu irú-ọmọ rẹ li a ti fi ibukun fun gbogbo idile aiye.

Iṣe Apo 3

Iṣe Apo 3:18-26