Iṣe Apo 28:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi awọn alaigbede na si ti ri ẹranko oloró na ti dì mọ́ ọ li ọwọ́, nwọn ba ara wọn sọ pe, Dajudaju apania li ọkunrin yi, ẹniti o yọ ninu okun tan, ṣugbọn ti ẹsan kò si jẹ ki o wà lãye.

Iṣe Apo 28

Iṣe Apo 28:1-11