Iṣe Apo 28:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Paulu si ṣà ìdi iwọ́nwọ́n igi jọ, ti o si kó o sinu iná, pamọlẹ kan ti inu oru jade, o dì mọ́ ọ li ọwọ́.

Iṣe Apo 28

Iṣe Apo 28:1-8